LYRICS:
Olorun mi oba awon oba
Eleda mi oba awon oba
alewilese-Oba
Aleselewi-Oba
Owibesebe-Oba
Awimayehun-Oba
Onimajemu-Oba
Olotito olododo
Oba toju gbogbo aye lo (Olorunmi)

Olorun mi oba awon oba (oba awon oba eh)
Eleda mi oba awon oba
alewilese-Oba
Aleselewi-Oba
Owibesebe-Oba
Awimayehun-Oba
Onimajemu-Oba
Olotito olododo
Oba toju gbogbo aye lo

Interlude: Kabio osi (Unquestionable)

Jesu ni maa ma sin Titi aye mi eh
Jesu nikan ni nwo ma sin titi ayemi
Jesu ni nwo ma sin Titi ayeraye ooh
Jesu nikan ni nwo ma sin titi ayemi
Oba awon oba eledumare arugbo ojo oh
Jesu nikan ni nwo ma sin titi ayemi
Meta lokan ologo meta olorun emi mimo
Jesu nikan ni nwo ma sin titi ayemi
Olutunu olubukun onise onise iyanu ni eeh
Jesu nikan ni nwo ma sin titi ayemi
Adunbarin adunbalo adun kinpe onise iyanu ni
Jesu nikan ni nwo ma sin titi ayemi
Adunbarin adunbalo adun kinpe onise iyanu ni eeeh
Jesu nikan ni nwo ma sin titi ayemi

Oba Awon oba ooh
Oyigiyigi nii
Alagbada ina alatilehin ni
Asoro Dayo nii
Aladewura ni
Jesu nikan ni ma ma sin titi ayemi
Jesu nikan ni nwo ma sin titi ayemi

Jesu nikan nimo nini baba
Jesu nikan nimo nini baba

OLUWA OOH

Jesu nikan nimo nini baba
Jesu nikan nimo nini baba
Jesu nikan nimo nini baba
Jesu nikan nimo nini baba

Olorun oba Awon oba
Olorun atobiju eh eh
Olorun oba awon oba (alagbada ina)
Olorun atobiju
Olorun oba awon oba ooh
Olorun atobiju ato farati eeh
Olorun oba awon oba
Olorun atobiju
Olorun oba awon oba ooh
Olorun atobiju eh eh
Olorun oba awon oba (Olorun agbaye)
Olorun atobiju (atofarati bi oke)
Olorun oba Awon (alawo tele bi Orun)
Olorun atobiju

Jesu oh jesu
Jesu oh jesu
Oloruko aperire jesu oh (oya so be)
Jesu oh jesu (gbingbiniki awuwo masegbe)
Jesu oh jesu (Olorun Iyanu)
Oloruko aperire jesu oh

Jesu oh jesu
Jesu oh jesu
Oloruko aperire jesu oh (ewi kingbo)
Jesu oh jesu (olorun 1930 ose)
Jesu oh jesu (awimayehun)
Oloruko aperire jesu oh

Oloruko aperire jesu oh
Oloruko aperire jesu oh
Atobi tan adara tan ebami pe ee
Oloruko aperire jesu oh
ani oloruko aperire jesu oh
Oloruko aperire jesu oh
Alade nla olola nla kabio osi
Oloruko aperire jesu oh
Ani Oloruko aperire jesu oh
Oloruko aperire jesu oh