Lyrics: His Stripes (Ina Re) By Toyin Mercy

A gu l’ oko l’ egbe
A de l’ ade egun oo
Nitori temi ni oo
Nitori temi ni /2ce

Solo 1:
He was wounded for my transgressions
Bruise for my iniquities
Chastisement of peace was upon him
By his Stripes I am healed /2ce

Nitori temi ni
Nitori tire ni
A gu l’ oko l’ egbe
A de l’ ade egun o
Nitori temi ni

Nitori temi ni
Se bi nitori ti re ni li
Ase gun l’oko l’ egbe
A de l’ ade egun o
Nitori temi ni

Repeat Chorus

Solo 2:
Ni pa Ina re a so mi di olowo
O t’osi ki n le je Oro aye
Omi ati eje iha re so mi di mimo
iwe ese mi si fa ya
A kegan re a tu ito si l’ara
A fi se esin ki n ma ba se esin
O ki gbe lohun rara pe oti pari
Aso egan mi si fa ya