Lyrics
Eru Ogo re bami
Eru ogo re bami o
Eleni ogo
Onite ogo
Alade ogo
Ololainu ogo
Elewa ogo
Kikidaogo ogo
Akodaogo ogo
Ogoninu ogo
Asaju ogo
Igbeyin ogo
Eru ogo re bami o
1.
Boti n gbe ninu ogo
O n Sogo Lori ite o
Ogo lo wo laso
Oloju ogo ni
Eda Orun fogo fun aramanda ogo to yii won ka
Baba ologo julo to da ohun gbogbo pelu ogo.
2.
Boti leruniyi to
Ite idajo taanu togo
Ogo otun iseju si iseju
Ewa ti o lakawe
Nigbogbo igba sigba
Ododo logo re
Awon orile -ede gbogbo nsola Lori ogo re
3.
Olorun to ta sanmo pelu ogo
Iwo lasaju ologo to leruniyi iba baba iba
Call: alogoleru
Response: toloke
Call: eleruniyi
Response: tonile
Call: onile ola
Response: alade ogo
Call: ofi kikida ogo