Lyrics
Adu mare Oba mi ni
Oba eh eh mh
Mo wole fun o
Alagbada ina baba mi oo
Mo wole fun o
Ogbe nu wundia sododo
Mo wole fun o
Ato farati bi oke won ni Baba
Mo wole fun o
Arugbo Ojo
Mo wole fun o
Baba awon tio ni baba
Mo wole fun o
Kabio omasi o baba mi
Mo wole fun o
Ogbe nu wundia sododo ododo baba o
Mo wole fun o
Arugbo ojo
Mo wole fun o, mo wole fun o, mo wole fun o
Arugbo Ojo
Mo wole fun o, mo wole fun o, mo wole fun o
Arugbo Ojo
Mo wole fun o, mo wole fun o, mo wole fun o
Arugbo Ojo
Mo wole fun o ba ba, mo wole fun o oh oh, mo wole fun o
Arugbo Ojo
Kabiosi oh baba
Alagbada Ina nio oo baba
Arugbo ojo nio ooo baba
Baba awon ti ko ni baba
Emi mimo ma nio o baba
Mimo mimo ma nio o baba mi
Eru jeje nio Oluwa oba
Arugbo ojo
Baba mi nio ooo baba
Eleda mi nio baba
Atorise nio oo baba mi
Ataye se nio oo baba
Atowo se ma nio oo baba
Oloju ina nio oo baba mi
Emi mimo nio ooo
Arugbo ojo
Arugbo ojo nio oo baba
Kinihun eya Judah nio oo baba