Video+Lyrics: Emi Mimo (Holy Spirit) – Tope Alabi

Video+Lyrics: Emi Mimo (Holy Spirit) – Tope Alabi

Lyrics
Emi mimo
Ekaabo
Ah emi mimo
Eku ikale
Emi alaayo
Emi orun ooo
Adaba mimo
Eku ikale
Agbara to ju’aiye ati orun lo
Ekaabo
Ekaabo
Eku ikale
Ekaabo o
Eku ikale
Ekaabo o
Oh eku ikale
Odeee lati wa so okun di ogo
Odeee lati wa so ekun di erin
Odeee lati was so ibanuje dayo
Eku ikale o
Ekaabo
Eku ikale o
Ekaabo oo
Baba eku ikale
Ekaabo
Emi mimo ti n so agbara di otun
Ogo kan to gbe aiye ati orun
Olowo ori awa oo
Ekun to koja gbogbo oke pata
Ode lati wa so ekun derin
Ode lati wa so egan di ogo
O ti de sarin wa oo
Eku ikale
Oti de sarin wa oo
Ema ku ikale o
Oti de sarin wa oo
Ema ku ikale oo
Eee emi mimo
Eee emi mimo
Adaba mimo odeee orun
Eku ikale
Ola san lo nile gbogbo eyan to n wo wa ebu ti yin
Erin po nile gbogbo eyan to n wo wa ema ko ti yin
Ekun tan, oshee gbe danu
Ogo bori ogun agbara ota kpin
Oti deee sarin wa o
Akani eleru, o yo de bo si n de
Emi mimo orun
Eku ikale
Emi alayo oo
Eku ikale oo
Emi olore
Eku ikale
Emi to n tan imole sipa okunkun ona
Ema ku ikale oo
Emi to shi ni ni iye lati mo oun to to ati oun to kan
Eku ikale
Emi to n so agbara di otun
Eku ikale
Emi to n so alaisan di alara pipe
Eku ikale oo
Emi to n so iku di iye
EMI to n so iku di ayoo
Oya emi to n shi ile omo
Ekaaabo oo
Emi to n shile omo fomo si meji, meta, merin
Emi to n so iku di aiye oo
Emi to n ji gbogbo oun to ti ku dide pata
Ekaaboo sarin wa
Ema ku ikale oo
Ekaaaabo sarin wa
Ema ku ikale
Eku ikale oo
Video+Lyrics: Eru Ogo Re Bami Oluwa – Tope Alabi

Video+Lyrics: Eru Ogo Re Bami Oluwa – Tope Alabi

Lyrics
Eru Ogo re bami
Eru ogo re bami o
Eleni ogo
Onite ogo
Alade ogo
Ololainu ogo
Elewa ogo
Kikidaogo ogo
Akodaogo ogo
Ogoninu ogo
Asaju ogo
Igbeyin ogo
Eru ogo re bami o
1.
Boti n gbe ninu ogo
O n Sogo Lori ite o
Ogo lo wo laso
Oloju ogo ni
Eda Orun fogo fun aramanda ogo to yii won ka
Baba ologo julo to da ohun gbogbo pelu ogo.
2.
Boti leruniyi to
Ite idajo taanu togo
Ogo otun iseju si iseju
Ewa ti o lakawe
Nigbogbo igba sigba
Ododo logo re
Awon orile -ede gbogbo nsola Lori ogo re
3.
Olorun to ta sanmo pelu ogo
Iwo lasaju ologo to leruniyi iba baba iba
Call: alogoleru
Response: toloke
Call: eleruniyi
Response: tonile
Call: onile ola
Response: alade ogo
Call: ofi kikida ogo
Video+Lyrics: Oluwa O Tobi – Tope Alabi

Video+Lyrics: Oluwa O Tobi – Tope Alabi

Lyrics
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
O tobi o, Oluwa giga lorile ede gbogbo
Gbigbega ni O, Iwo lo logo ni orun
Pupopupo ni O, O koja omi okun at’osa, O ga po
Ajulo O o se julo
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Oba lori aye, O tobi o eh
Agba’ni loko eru, Olominira to n de’ni lorun
O fi titobi gba mi lowo ogun t’apa obi mi o ka
Olugbeja mi to ba mi r’ogun lai mu mi lo t’o segun
Akoni ni O o
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
B’O ti tobi to oo, laanu Re tobi
B’O ti tobi se o, ododo Re tobi o
O tobi tife tife, Oni majemu ti kii ye
Aro nla to gbo jije mimu aye gbogbo alai le tan
Ogbon to koja ori aye gbogbo ooo
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Akoko O tobi, O tobi o
Oluwa
Ipilese ogborin o yeye
O tobi
Ibere Eni to f’ogbon da ohun gbogbo
Oluwa
Igbeyin ola nla, o la la oo
O tobi
Opin aye a’torun ko si ‘ru Re
Oluwa
O tobi, O o se s’akawe lailai o
O tobi
Agbaagba merinlelogun nki O, O tobi
Oluwa
Awon angeli won n ki O, O tobi
O tobi
Olorun Elijah Ireti Ajanaku
Oluwa
O ma tobi laye mi, O tobi ooo
O tobi
Iwo lo gb’orin t’O o ga, t’O gun, t’O tun fe
Oluwa
O ga, O gun, O fe, O jin, O tobi la la
O tobi
Video+Lyrics: Awa Gbe O Ga – Tope Alabi

Video+Lyrics: Awa Gbe O Ga – Tope Alabi

Lyrics
Ore mi ti ki n se ore awon ota mi eeh eeh
Awa gbe o ga
Oluhun ko gun orun a jo si odumare opa tinrin kan le
Awa gbe o ga
Ojo mini mini ti n j’ara o de yan orun wa wa wa ki igba o pa da bo
Awa gbe o ga
Isale ale oru oru ikawo re lo wa
Awa gbe o ga
Iyin re lo da wa fun olorun
Iyin re lo da wa fun olodumare
Iko ko orun owo lo wa, ibi kan lo n gbe
Iyin re ko ni tan lenu wa
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga
Awa ni iran ti n s’aferi re o
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga o
Awa gbe o ga
Agbara lo fi na aye ja lati salu orun wa’ye
Owo re lo fi ina orun ja o po ko ja awon okun
Iyin re ko ni tan lenu wa
Iyin re ko ni tan lenu wa
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga o
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga o
Awa gbe o ga
Awa ni iran ti n s’aferi re o
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga o
Awa gbe o ga
Ore mi ti ki n se ore awon ota mi eeh eeh
Oluhun ko gun orun a jo si odumare opa tinrin kan le
Ojo mini mini ti n j’ara o de yan orun wa wa wa ki igba o pada bo
Isale ale oru oru ikawo re lo wa
Pata pata ologo to n dan gbirin gbirin gbirin gbirin gbirin
Didan ninu ogo ewa Isaju o orun
Awa gbe o ga
Awa ni iran ti n s’aferi re o
Awa gbe o ga
Awa ni iran ti n s’aferi re o
Awa gbe o ga
O ba ni mule ma da ni olowo ori aye
Awa gbe o ga
A a a wa gbe o o o
Awa gbe o ga
A gbe o ga o
A pe o a pe o
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga oooooo
Awa gbe o ga
Ore mi ti ki n se ore awon ota mi eeh eeh
Oluhun ko gun orun a jo si odumare opa tinrin kan le
Ojo mini mini ti n j’ara o de yan orun wa wa wa ki igba o pada bo
Isale ale oru oru ikawo re lo wa
Pata pata ologo to n dan gbirin gbirin gbirin gbirin gbirin
Didan ninu ogo ewa isaju o orun
Iyin re lo da wa fun olorun
Iyin re lo da wa fun olodumare
Iyin re ko ni tan lenu wa
Awa gbe o ga
Video+Lyrics: Awa Gbe O Ga – Tope Alabi

Video+Lyrics: You Are Worthy – Tope Alabi

Lyrics
Hmmmmm
Ohhhhh
Ehhhhhhh
You are worthy, you are worthy, you are worthy of my praise
You are worthy, you are worthy, you are worthy of my praise
Eleburuike oooo,
Oranmonisefayati oooo, aranibanilo ooooo, you are worthy
Oba to gba mi la o, olowo ina oooo,
Iwo nikan logo ye ooo you are worthy
Lion of the tribe of judea, kinging in his majesty,
Ruler of the universe,
I tremble at your feet
I tremble at your feet
Worthy of our worship
Olola to ga ju lo, oloro to poju lo, ologo to ga ju you are worthy,
Oba to ju gbogbo oba lo,
Ijoba ni bi gbogbo olori aye isale ile alainipekun ni o
Oforun nikan se kiki da wura,
Oda orun pelu aye pelu ara oto ebo mi Aji to la mo gbo su ba fogo ra
Bale ibeere ogo arin ogo olunkangun Igbeyin ogo eniti gbogbo aye yio
Pada wa bo
Kabiesi oooo araye koba ni kabiesi won ni kade pe lori ki
Bata pe lese o iwo nikan ni kabiesi ta o gbodo so pe kade pe lori fun
Ewo a o gbodo ni ki bata pe lese lailai sade ta o
Mo gba to gori e se bata ta o mo gba to wo ese re